AGLA
Oruko mimo yii ni Anobi Yusufu (JOSEPH) pe,
ti a si yoo kuro ninu igbun
,
a si gbala kuro ninu ewu awon arakunrin re
Talisman fun AGLA
Enikeni ti o ba ko oruko mimo olorun yii
ni igba metadiladota 47times si ara
iwe felefele kan, pelu tadawa dudu(black ink)
eyiti ati po eje ijapa papo mo. Lehin ti
a ba pari kiko re tan, ao we ni owu siliki dudu(Black silk)
Ti enia ba nfi oruko mimo na si ara,
eni na yio mu ori bo kuro ninu gbogbo igbekun
awon ota, ko ai ni ku iku oro kan,
aya fi ki o fi owo ro ri ku, ati wipe eni na yio
si lo igbesi aiye re pelu emi gigun
Hontu fun AGLA
Bakanna ti enia ba nko oruko mimo yi
ni igba 101 si ara wala dudu ti awon musulumi
fi n ko huntu, pelu tadawa eyikeyi ti o ba mo daradara,
fun odidi ose kan, lehin ti a ba npari kiko re
ni ao wa fi omi agbon fo mu fun gbogbo ojo mejeje ti n be ninu ose.
N.B ao bere ise na ni ojo sunday ao pari re si ojo saturday
Enikeni tio ba se iseyi gegebi a tise alaye re yii,
apa aiye kan kiyo ka oluwa re mo lailai.
Asiri nla ni sugbon mio fi sita nitori awon janduku enia,
bikose awon oni iwa irele biti Anobi YUSUFU
by: Adept V. O Adedokun
tel: +2349030943883 , +2347087896633
Mantoosh Majlooj
clink here To like our facebook page
No comments:
Post a Comment