De Patriarch Home

De Patriarch Home

De Patriarch Home

Tuesday, 31 January 2017

MAITATARU NA


TALISMANU FUN EYONU/GENERAL LOVE

MAITATARU-NA
Oruko mimo yi ni ao ko si inu parchment paper
 ni igba 313, tabi iwe felefele, pelu tadawa
pupa eyiti ati po eje eyele papo mo,
 lehin ti aba pari kiko re tan,
 ao fi owu siliki alawo yellow we ni tira,
ao ma fi si ara, ti o ba sese ki ama de sinu fila ti a ba nde si ori.
2. Ti ao ba ri eje eyele na, ao fi tadawa pupa ko,
 lehin ti aba pari kiko re tan, ao lo wa isu kuho
 ati opolo ori eiye aparo, ao lo mejeji papo
 ao wa bu die si oju talismanu na, ao fi owu siliki green we bakanna.
N.B ki agbiyanju lati ma fi lofinda olorun didun si ni gbogbo gba,
ti aba nso nipa lofinda ti ao ma fi si talismanu
edakun ki nse awon lofinda ti awon kerubu ati cele ma nlo
 e.g holy michael, grace,777, e.t.c
gegebi iwadi wa ni wipe ti aba nfi iru awon lofinda bayi
 si inu talismanu won yio ma di agbara talismanu na ku ni,
 nitori gbogbo ohunti won fi se ni okunfun oti(Alcohol).
Sugbon ti aba fe ra lofinda fun talismanu e jeki ama
 ra sasorobia, bintu,6flowers e.t.c, awon lofinda
 ti mo recommend fun wa lati ma lo,
 lati le ma ri esi ayo mi awon ise ti aba nfi won se.
by: Adept Adedokun Victor
tel:+2349030943883 



1 comment:

  1. Casino Rewards - JtmHub
    With over a hundred casino 광주 출장마사지 games, and thousands of slot machines, you can 김제 출장샵 play without even stepping into it. All you have to do is 계룡 출장샵 hop 원주 출장샵 on to 충주 출장마사지 the

    ReplyDelete