Thursday, 2 February 2017
IBERE FUN AWON OJOGBON
. H H H
| | |
H-O-C-C-C-O-H
| | |
H H H
|
H
Enikeni ti o ba ri itunmon aworan kekere yi so fun mi ati ise ti
Nse, mo fi nda loju wipe ebun nla nbe fun iru enibe.
Lati owo egbe MantooshMajlooj
*ASIRI AGBARA LATI LEMU KI A DI ALASE LORI GBOGBO AWON ALUJONU*
```Talismanu yi lagbara pupo debi wipe ti o ba nbe ni arawa lesekese ni ao di alase lori gbogbo awon emi airi, gbogbo awon alujonu patapata ni won yio ma se erusin ni abe wa paapa julo talismanu je gbongbo irinse fun awon ti won nsise pelu awon alujonu, ti iru enibe na n lo Talismanu yi gbogbo ohunti o ba pa lase fun awon alujonu na ni won yio ma tele, won kosi ni fi igba kankan pa ohun enu re da lailai
Arika ninu awon iwe ara igba lailai ti won nko nipa itan Oba Sulemonu (Solomonu) wipe talismanu yi ni Solomonu nlo lati fi gbogbo awon alujonu lori ba.
Enikeni ti o ba fe se ise yi ni lati ko Talismanu yi si inu iwe alawo orombo pelu tadawa pupa leyinti a ba pari kiko re tan ao wa ojulowo eha irun oje (Lead), eha iri funfun (Tin), eha irin dudu(Iron), eha wura(Gold), eha irin baba(Copper), ki e wa Mercury ati eha fadaka(Silver) awon eha irin yi ni ao wa gbogbo re ni diedie ao wa da si oju Talismanu na, ao wa turari almuski gberefu(Musk powder) ao da si oju Talismanu na bakanna, ao wa fi owu siliki alawo orombo we, ao tu fi owu alawo funfun we, ao sese wa fi owu alawo pupa we ni tira. Ao wa gbe fun awon onise ona awo ki won bawa fi awo funfun ran ni tira.```
*NOTICE*
```Enikeni ti o ba nfi Talismanu yi si ara, iru enibe yio di alase lori gbogbo eda enia ati gbogbo alujonu ti Olorun da. Ti aba wa ri enikeni ti o fe gbiyanju lati pe eyikeyi ninu awon alujonu, ki iru enibe fi Talismanu yi ko si orun, ti alujonu na bati fi oju kan Talismanu yi lesekese ni yio teriba fun eniti o ke pe, Ti aba ri enai kan ti o nfi Talismanu yi si ara ni igba gbogbo, dajudaju gbogbo enia ni yio ma teriba fun iru enibe, won yio si mase erusin labe Olaware```
Lati owo egbe MantooshMajlooj
+2349030943883
Fun iwo ti o o ba fe ki afi aworan talismanu ti a ntoka si ninu ise yi, ki o comment , nitori #3,000naira ni iwo yio san ki o to ke ri aworan na gba lowo wa.
ASIRI AGBARA ORUKO MIMO FUN IFERAN
IFERAN
*"GESHI KASHISH TARSAJ LAA........."*
Ti eba ni enikeni ti nwu yinlati fe sugbon ti ife na ko
dan moran larin eyin mejeji,
ki e bere sini ka GBOLOHUN MIMO
yii ni igba ogorun ni gbogbo ale titi
di igba ti aba ti ri ayipada ninu ife na.
N.B: ni ibi ti ila wa ni iwaju G
BOLOHUN na ni ao ti ma daruko enina
Lati owo egbe 👳♀MONTOOSH MAJLOOJ👳🏾
+2349030943883
MantooshMajlooj
ASIRI AGBARA LATI LE KEPE ALUJONU
Iwo yio gba awe fun ojo meta nitori ijo meta
pere ni ama fi nse ise na lasepe.
Ti o ba ti di ni ale iwo yio lo si
ibaluwe(bathroom) iwo yio bere sini ma ka bayi wipe
SHOR SOR KIO WA JE MI IWO ALUJONU
bayi ni iwo yio ma so ni igba egberun le ni meji (1002x).Ti oba wa di ni asale ojo keta iwo yio ri ti alujonu
na yio bere sini mi ile ati ogiri ile ibaluwe na,
dajudaju alujonu na ti je ipe re niyi,
ki o bere sini so gbogbo ohunti otitori re pe alujonu na,
laisi aniani gbogbo ohunti o ba ran alujoni na ni yio je ni kiakia.
N.B: ise yi ki nse wipe ama fi oju ri alujonu naa,
sugbon yio mi gbogbo ile ti o ba ti de,
ni ao fi mo wipe alujonu na tide.
Ri wipe kosi alatako fun e lasiko
ti o ba nka awon gbolohun na lowo.
Ki oma si se beru rara,
nitori alujonu koni agbara kankan lati se o ni janba kankan.
Like our facebook page here
How contact Adept Adedokun
+2349030943883
+2347087896633
JEHOVAH-EL-NEGOMOTH
JEHOVAH-EL-NEGOMOTH
Enia mi, asiri oruko mimo ti olorun
fi kepe Samuel ni ijo kini ana niyi,
( Samuel 3:21)oruko mimo yi kanna
ni olohun lo lati lefi ara han Samuel
ni Shiloh, wo iwo omo iya mi ninu oluwa,
oruko mimo yi lagbara to be lati lefi
di eniti olorun yio ma
fi aran han ni gbogbo igba,
loju aiye ati ni oju orun,
koda ti eniyan ba nlo asiri oruko yi
kosi ohunkohun bi ohun asiri abi ohun
ikoko kankan ti yio sokunkun si iru enibe,
nitori gbogbo re patapata ni ao ma fi han,
Enikeni ti o ba nfe lati lo asiri oruko na yi
fi odidi ojo meje gba awe funfun ojo meje,
larin asiko awe yi ni yio ma ka oruko mimo
na ni igba mokandinlogorun (99times),
bayi ni iwo yio ma ka fun gbogbo wakati
adura patapata, lehin kika re ni iwo yio ma
ka Psalm 19 si ni igba meje,
lehinti ojo keje na ba pe,
haaaa!
Enia mi,
iwo yio ti di eniti okun fun agbara emi mimo,
iwo yio ma gbo ohun bakanna ni iwo yio
ma riran be sini iwo yio ma sotele
gegebi Samuel ti nse,
awon angeli mimo yio si ma fi arawon han fun e,
lati le ma se amona re ni gbogbo ojo aiye re.
JEHOVAH-EL-NEGOMOTH
Bakanna ti iwo ba npe oruko mimo yi ni
ojojumo ni owuro ati ni asale ni
igba meta-le-logbon (33times)
ni ojojumu iwo yio ma ri gbogbo ohunti
oti sele seyin ati ohunti ohunbo wa sele,
beni ti ohun aburu bafe sele iwo yio ti mo saju.
JEHOVAH-EL-NEGOMOTH
Bakanna ti iwo ba ko oruko mimo na ni
igba 313 si inu iwe felefele funfun kan,
ki iwo wa fi turari Vision,
ati turari temple ti ati lo kunna
dada si oju kiko re, ao wa we ni owu
mixed colour ao ma kan lofinda
olorun didun si, iwo yio wa ma fi si
abe irori re sun ni ale ti iwo bafe sun,
tabi ti ohun kohun ba sokunkun sio,
ti iwo si fe mo nipare kio gbiyanju
lati se aniyan ohunti iwo nfe mo si
inu re ki ofi si abe irori re sun ni ale,
dajudaju gbogbo ohunti iwo ba daniyan
lati mo ni awon angeli mimo naa yio fi han fun e loju orun. JEHOVAH-EL-NEGOMOTH
Ise yi wa lati owo Adept Adedokun Victor Olayinka
Fun iwulo omo eniyan.
09030943883
ÀṢIRÍ ÀGBÀRÁ LÁTI LE JẸ GBOGBO ÈNÌÀ NIPA
ÀṢIRÍ ÀGBÀRÁ LÁTI LE JẸ GBOGBO ÈNÌÀ NIPA
Talisman yi lagbara lati le je ki,
a ni agbara Ase lori ohun gbogbo,
yala lasiko adura ni abi lasiko epe.
Ti talismanu ba nbe ni arare lasiko
adura abi ni asiko epe tabi igbakugba
ti iwo nfe lati ma soro Ase lenu ki
iru oro be si ma wa si imu se.
Enikeni ti oba fe se iru ise bayi kio
gbayinju lati ko talismanu yi si ara
awo ekun ti a ti so di parchment paper,
pelu tadawa pupa eyiti ati po eje akuko
adie papo mo lehin ti aba pari kiko re tan.
Ao lo wa iko eye odidere kan ati ileke segi kan,
ao lo mejeji yi papo ti yio kunna daada bi
ebu(powder). Lehin na ni ao we ni owu siliki
funfun(white silk thread) lehin na ni ao lo
gbe fun awon onise ona awo ki won bawa
gba ni awo ekun, sugbon kiwon fi iho kekere
kan si ti ao ma gba fi kan lofinda
sasorabia si ni gbogbo igba.
Laisi atunwi asan,
ti talismanu yi bahun be ni arawa,
gbogbo oro ti aba nso ni yio di ase,
ati wipe iwo yio di alase lori gbogbo
eda enia ati wipe iwo yio di enia ti
adura re yio ma gba, ni gbogbo igba .
Talismanu yii ni awon Ojogbon kan ni
ile SAUDI ARABIAN npe ni Olugbohun.
Enia mi mase si ise yi lo ooo
nitori iwo yio di erujeje ni ibi gbogbo ti Iwo ba nde. 09030943883

ASIRI ORUKO MIMO OLORUN EYI TI NSE AJEBI IDAN KI ADURA ENIYAN LE MA DI ITEWO GBA LOWO OLORUN
*ASIRI ORUKO MIMO OLORUN EYI TI NSE AJEBI IDAN
KI ADURA ENIYAN LE MA DI ITEWO GBA LOWO OLORUN*
```Ti aba ko oruko mimo yi ni iye igba ti yio gba ninu
awo ako malu eyiti won pa ni ojo satide ti ati sa ti oti
gbe daadaa, ao wa fi eje odo aguntan ti ko ti gun abo rii,
ao po eje re mo tadawa pupa, ao beere sinu fi ko
oruko mimo na, titi ao fi ko si gbogbo ara awo malu na,
lehin ti aba pari kiko re tan ao sa si inu ile ni aye
ti a pese sile fun awo na,(ao gbudo sa sinu orun mo)
lehin ti tadawa na bati gbe ao ma joko si ori awo na
lati se adura ni gbogbo wakati adura lati ma ki irun,
wo iwo omo iyami, gbogbo adura ti iwo ba gba lori
awo yi ni yio di itewo gba lodo olorun nitori
wipe oruko ni ipinlese awo na nse.
Bakanna lehin ti iwo ba ki irun wakati tan
ti iwo ba nka gbolohun na ni igba meta le logbon(33)
ki iwo to beere si ni beere ohun ti iwo nfe lowo olorun,
iwo yio ri wipe, iru adura be yio di itewo gba lowo olorun.
Oruko mimo na ni ```
Fun iwo ti o ba fe gba oruko na ki o comment pelu number re,
nitori ao koko gba #3000 naira lowo re
For our facebook page clink

Subscribe to:
Posts (Atom)