De Patriarch Home

De Patriarch Home

De Patriarch Home

Thursday, 2 February 2017

ÀṢIRÍ ÀGBÀRÁ LÁTI LE JẸ GBOGBO ÈNÌÀ NIPA

ÀṢIRÍ ÀGBÀRÁ LÁTI LE JẸ GBOGBO ÈNÌÀ NIPA Talisman yi lagbara lati le je ki, a ni agbara Ase lori ohun gbogbo, yala lasiko adura ni abi lasiko epe. Ti talismanu ba nbe ni arare lasiko adura abi ni asiko epe tabi igbakugba ti iwo nfe lati ma soro Ase lenu ki iru oro be si ma wa si imu se. Enikeni ti oba fe se iru ise bayi kio gbayinju lati ko talismanu yi si ara awo ekun ti a ti so di parchment paper, pelu tadawa pupa eyiti ati po eje akuko adie papo mo lehin ti aba pari kiko re tan. Ao lo wa iko eye odidere kan ati ileke segi kan, ao lo mejeji yi papo ti yio kunna daada bi ebu(powder). Lehin na ni ao we ni owu siliki funfun(white silk thread) lehin na ni ao lo gbe fun awon onise ona awo ki won bawa gba ni awo ekun, sugbon kiwon fi iho kekere kan si ti ao ma gba fi kan lofinda sasorabia si ni gbogbo igba. Laisi atunwi asan, ti talismanu yi bahun be ni arawa, gbogbo oro ti aba nso ni yio di ase, ati wipe iwo yio di alase lori gbogbo eda enia ati wipe iwo yio di enia ti adura re yio ma gba, ni gbogbo igba . Talismanu yii ni awon Ojogbon kan ni ile SAUDI ARABIAN npe ni Olugbohun. Enia mi mase si ise yi lo ooo nitori iwo yio di erujeje ni ibi gbogbo ti Iwo ba nde. 09030943883 

No comments:

Post a Comment