09030943883
Thursday, 2 February 2017
JEHOVAH-EL-NEGOMOTH
JEHOVAH-EL-NEGOMOTH
Enia mi, asiri oruko mimo ti olorun
fi kepe Samuel ni ijo kini ana niyi,
( Samuel 3:21)oruko mimo yi kanna
ni olohun lo lati lefi ara han Samuel
ni Shiloh, wo iwo omo iya mi ninu oluwa,
oruko mimo yi lagbara to be lati lefi
di eniti olorun yio ma
fi aran han ni gbogbo igba,
loju aiye ati ni oju orun,
koda ti eniyan ba nlo asiri oruko yi
kosi ohunkohun bi ohun asiri abi ohun
ikoko kankan ti yio sokunkun si iru enibe,
nitori gbogbo re patapata ni ao ma fi han,
Enikeni ti o ba nfe lati lo asiri oruko na yi
fi odidi ojo meje gba awe funfun ojo meje,
larin asiko awe yi ni yio ma ka oruko mimo
na ni igba mokandinlogorun (99times),
bayi ni iwo yio ma ka fun gbogbo wakati
adura patapata, lehin kika re ni iwo yio ma
ka Psalm 19 si ni igba meje,
lehinti ojo keje na ba pe,
haaaa!
Enia mi,
iwo yio ti di eniti okun fun agbara emi mimo,
iwo yio ma gbo ohun bakanna ni iwo yio
ma riran be sini iwo yio ma sotele
gegebi Samuel ti nse,
awon angeli mimo yio si ma fi arawon han fun e,
lati le ma se amona re ni gbogbo ojo aiye re.
JEHOVAH-EL-NEGOMOTH
Bakanna ti iwo ba npe oruko mimo yi ni
ojojumo ni owuro ati ni asale ni
igba meta-le-logbon (33times)
ni ojojumu iwo yio ma ri gbogbo ohunti
oti sele seyin ati ohunti ohunbo wa sele,
beni ti ohun aburu bafe sele iwo yio ti mo saju.
JEHOVAH-EL-NEGOMOTH
Bakanna ti iwo ba ko oruko mimo na ni
igba 313 si inu iwe felefele funfun kan,
ki iwo wa fi turari Vision,
ati turari temple ti ati lo kunna
dada si oju kiko re, ao wa we ni owu
mixed colour ao ma kan lofinda
olorun didun si, iwo yio wa ma fi si
abe irori re sun ni ale ti iwo bafe sun,
tabi ti ohun kohun ba sokunkun sio,
ti iwo si fe mo nipare kio gbiyanju
lati se aniyan ohunti iwo nfe mo si
inu re ki ofi si abe irori re sun ni ale,
dajudaju gbogbo ohunti iwo ba daniyan
lati mo ni awon angeli mimo naa yio fi han fun e loju orun. JEHOVAH-EL-NEGOMOTH
Ise yi wa lati owo Adept Adedokun Victor Olayinka
Fun iwulo omo eniyan.
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
Thanks so much GOD bless you
ReplyDelete