De Patriarch Home

De Patriarch Home

De Patriarch Home

Thursday, 2 February 2017

ASIRI ORUKO MIMO OLORUN EYI TI NSE AJEBI IDAN KI ADURA ENIYAN LE MA DI ITEWO GBA LOWO OLORUN

*ASIRI ORUKO MIMO OLORUN EYI TI NSE AJEBI IDAN KI ADURA ENIYAN LE MA DI ITEWO GBA LOWO OLORUN* ```Ti aba ko oruko mimo yi ni iye igba ti yio gba ninu awo ako malu eyiti won pa ni ojo satide ti ati sa ti oti gbe daadaa, ao wa fi eje odo aguntan ti ko ti gun abo rii, ao po eje re mo tadawa pupa, ao beere sinu fi ko oruko mimo na, titi ao fi ko si gbogbo ara awo malu na, lehin ti aba pari kiko re tan ao sa si inu ile ni aye ti a pese sile fun awo na,(ao gbudo sa sinu orun mo) lehin ti tadawa na bati gbe ao ma joko si ori awo na lati se adura ni gbogbo wakati adura lati ma ki irun, wo iwo omo iyami, gbogbo adura ti iwo ba gba lori awo yi ni yio di itewo gba lodo olorun nitori wipe oruko ni ipinlese awo na nse. Bakanna lehin ti iwo ba ki irun wakati tan ti iwo ba nka gbolohun na ni igba meta le logbon(33) ki iwo to beere si ni beere ohun ti iwo nfe lowo olorun, iwo yio ri wipe, iru adura be yio di itewo gba lowo olorun. Oruko mimo na ni ``` Fun iwo ti o ba fe gba oruko na ki o comment pelu number re, nitori ao koko gba #3000 naira lowo re For our facebook page clink

No comments:

Post a Comment