De Patriarch Home

De Patriarch Home

De Patriarch Home

Thursday, 2 February 2017


*ASIRI AGBARA LATI LEMU KI A DI ALASE LORI GBOGBO AWON ALUJONU*
```Talismanu yi lagbara pupo debi wipe ti o ba nbe ni arawa lesekese ni ao di alase lori gbogbo awon emi airi, gbogbo awon alujonu patapata ni won yio ma se erusin ni abe wa paapa julo talismanu je gbongbo irinse fun awon ti won nsise pelu awon alujonu, ti iru enibe na n lo Talismanu yi gbogbo ohunti o ba pa lase fun awon alujonu na ni won yio ma tele, won kosi ni fi igba kankan pa ohun enu re da lailai
Arika ninu awon iwe ara igba lailai ti won nko nipa itan Oba Sulemonu (Solomonu) wipe talismanu yi ni Solomonu nlo lati fi gbogbo awon alujonu lori ba.

Enikeni ti o ba fe se ise yi ni lati ko Talismanu yi si inu iwe alawo orombo pelu tadawa pupa leyinti a ba pari kiko re tan ao wa ojulowo eha irun oje (Lead), eha iri funfun (Tin), eha irin dudu(Iron), eha wura(Gold), eha irin baba(Copper), ki e wa Mercury ati eha fadaka(Silver) awon eha irin yi ni ao wa gbogbo re ni diedie ao wa da si oju Talismanu na, ao wa turari almuski gberefu(Musk powder) ao da si oju Talismanu na bakanna, ao wa fi owu siliki alawo orombo we, ao tu fi owu alawo funfun we, ao sese wa fi owu alawo pupa we ni tira. Ao wa gbe fun awon onise ona awo ki won bawa fi awo funfun ran ni tira.```
*NOTICE*
```Enikeni ti o ba nfi Talismanu yi si ara, iru enibe yio di alase lori gbogbo eda enia ati gbogbo alujonu ti Olorun da. Ti aba wa ri enikeni ti o fe gbiyanju lati pe eyikeyi ninu awon alujonu, ki iru enibe fi Talismanu yi ko si orun, ti alujonu na bati fi oju kan Talismanu yi lesekese ni yio teriba fun eniti o ke pe, Ti aba ri enai kan ti o nfi Talismanu yi si ara ni igba gbogbo, dajudaju  gbogbo enia ni yio ma teriba fun iru enibe, won yio si mase erusin labe Olaware```
Lati owo egbe MantooshMajlooj
+2349030943883

Fun iwo ti o o ba fe ki afi aworan talismanu ti a ntoka si ninu ise yi, ki o comment , nitori  #3,000naira ni iwo yio san ki o to ke ri aworan na gba lowo wa.

1 comment: