Sunday, 12 March 2017
ASIRI AGBARA LATI LE JE ENITI KO RI ORUN SUN KI ORI ORUN SUN
Ti aba ri enikeni ti koba ri orun sun
ni gbogbo ale tabi ti ori,
a nfo ni gbogbo igba ki e ko
gbolohun mimo yi si inu i
we alawo orombo, sugbon eniti afe
lo fun na o gbudo mo wipe
a se iru ise bayi fun ohun,
lehin ti a ba pari kiko na tan
ao rora lo fi si abe irori ti enina
ba ngbe orile, dajudaju iru
enibe yio ri orun sun pelu irorun
gbolohun na niyi
MILANT VÁ VITALOTH JEOBÓA FEBAOTH
FOR OUR FACEBOOK PAGE CLINK HERE
or contact us for more information on
+2349030943883
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment