Sunday, 12 March 2017
ASIRI AGBARA LATI LEDI ENITI OJU KANKAN KONI LE RI
Asiri yi lagbara pupo debi wipe
kosi enia kankan ti yio ri oluwa re,
asiri yii bahun be ni ara re,
asiri yi ni awon Anobi kan ma
nlo nigba ti ogun bade,
tiwon yio si fi kuro larin ogun na,
ki nse wipe won nlo lati fi jale, t
abi pa omo enikeji won lara,
won ki nfi jale, sugbon won ma
nfi dabobo ara won nio,
iwo omo iya mi, mo nfi oruko
Oba Ajoke aye be o ri daju wipe
oogbudo fi agbara yi se ika tabi fi n se ibi,
nitori oruko mimo olorun,
ni afi pelo Talismanu yii,
Ni bayi enikeni ti oba fe se Asiri yi,
yio gba awe fun ojo meje,
ni akoko ti oba ngba awe yi yio ma
ka awon oruko mimo yii ni gbogbo
wakati adura kankan ni igba
kokan-din-logorun (99times),
ati ese bibeli yii ni igba meta le logbon(33),
Psalm 135: 14-17,
iwo yio ma ka oruko yii ati ese
bibeli yi ni gbogbo wakati
adura patapata fun ojo meje yii.
Lehinti ojo meje bape iwo yio
ti ni awo eye owiwi eyiti a ti tunse
ti o ti di parchment paper(owl parchment)
ao wa lo wa tadawa pupa eyiti
ati po eje eye kan ti nje adan (bat blood)
tadawa yi ni ao fi ko talismanu yi ni ojo
ti awe ba pe ojo keje, lehinti e ba pari kiko re tan,
wa we ni owu siliki alawo orombo(yellow silk thread)
lehin na ni eo wa kan lofinda sasorabia si,
lehin ti iwo ba pari re iwo yio lo gbe
fun awon onise ona awo kiwon
ba e fi awon funfun ran ni ifunpa.
Ti iwo ba nfi talismanu yi sara
ni iwo yio pe oruko mimo yi ni ohun raara,
BENATIR CARARKAU DEDOS ETINARMI
lesekese ni iwo yio di eniti oju kankan koni leri ooo.
Ti iwo basi yo ifunpa na ni enia yio to fi oju rio.
EYINI KOKORO ASIRI AGBARA LATI
LEDI ENITI OJU KANKAN KONI LERI
Aworan oke yi ni ao ya,
sugbon kiko ati sise ise na gbudo
je eyikeyi ojo sunday ninu ikan
ninu awon osu meta yi,
osu Taurus ♉,
osu Leo ♌,
osu Capricorn ♑,
Oruko mimo ti a nso nipa re
wipe ao ma ka ni wakati adura na ni
ABAC ALDAL IAT HUDAC
GUTHAC GUTHOR GOMEH
TISTATOR DERISOR DESTATUR
Ni gbogbo asiko ojo meje yii,
iwo ko gbudo je eyikeyi ninu
ohun alata, tabi ohun abemi,
beni iwo ko gbudo je alubosa, ayu, Abbl.
Lati owo Adept Adedekun Victor Olayinka
+2349030943883
Click Here to like our facebook page
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment