De Patriarch Home

De Patriarch Home

De Patriarch Home

Monday, 27 March 2017

ASIRI AGBARA ORUKO MIMO OLORUN TI NJE VAU


VAU

VAU  yii ni oruko ti baba wa ABRAHAMU
 lo ti ofi di eni mimo ati oni iwa mimo niwaju oluwa

ASIRI LILO VAU FUN TALISMANU
Enikeni ti oba fe gbiyanju ise na wo,
yio ko VAU ni igba 1111 si inu iwe felefele
 funfun pelu red ink eyiti atipo
 eje eiye ile papo mo, lehin ti aba pari
 kiko re tan ao we ni owu siliki
alawo ewe (green silk) lehin ti aba
 pari sise talismanu naa ao ma kan
lofinda ti oni iye lori daada si ara re
(e.g sasorobia), ao ma fi talismanu
 na si ara ni gbogbo igba.

Enikeni ti talismanu na bawa lara
 re yio di alagbara nla ati olokiki eniyan,
gbogbo awon eniyan ni yio ma
teriba fun iru eni bee.
 Eyiti otu je iyalenu ninu ise
 talismamu naa ni wipe ti oba wa lara
eniyan kosi ogun aiye kan ti yio bori wa

ASIRI LILO VAU FUN HUNTU
Ao ma ko VAU si ara wala ti awon
 musulumi fun ko huntu tabi si ara
 awo sobi perese tabi si ara digi iwoju,
 ao ko VAU yii si ni igba 111 pelu
 takada ti o mo daada, lehin ti aba pari
 kiko re tan ao fi omi odo to nsan daada fo,
 ao ma mu. Gbogbo eniti oba mu ninu omi na
oluwa yio so agbara mimo re kale fun ire eni be

Lati owo: Adept Adedokun Victor
tel:+2349030943883


No comments:

Post a Comment