Sunday, 12 March 2017
*ISOYE TI O DAJU*
RECABUSTIRA
CABUSTIRA
BUSTIRA
STIRA
TIRA
RA
A
_Eo ya aworan yi si ara wala dudu
ni igba mesan fun okunrin,
igba meje fun obirin,
eo fi omi ti eyele ba mu ku fo,
ao wa lo da si inu oyin, ao ma la,
enikan soso lo le lo ooo,_
Bakanna ti enia ba nko ni alale
si inu iwe funfun kekere_ _kan,
ti o si nfi omi agbon,
gbemi bi eniti nlo ogun tablet
fun ale ojo meje
Dajudaju iru enibe yio ni igbon
ati imo ijinle ninu gbogbo
ohunti o ba hunko ni ile eko tabi ni ibi ise
bakanna ti eniti nfe imo ijinle
ba nlo yio tubo ma ni oye ninu iwadi re_
*Lati owo Adept Adedokun Victor Olayinka*
+2349030943883
To like Our facebook page click Here
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment